Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ
Lati ọdọ Abu Mūsa - ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pe:
Available in 60 languages
«Lati ọdọ Abu Mūsa - ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pe: Wọn bi ojiṣẹ Ọlọhun - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - leere nipa arakunrin ti n jagun ni ti ijẹ akin, ati eyi ti n jagun ni ti ìgbónára, ati eyi ti n jagun ni ti karimi, ewo ninu rẹ ni o wa ni oju-ọna Ọlọhun? Ni ojiṣẹ Ọlọhun - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - wa sọ pe: «Ẹni ti o ba jagun lati jẹ pe ọrọ Ọlọhun ni yio leke, oun ni o wa ni oju-ọna Ọlọhun».»Meaning translation ·
Saved at original quality








