Hadith for the World
Tap the image to view it full size
Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ

Lati ọdọ Anas ọmọ Mālik - ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pe: Ojiṣẹ Ọlọhun - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - sọ pe:

Available in 60 languages
«Lati ọdọ Anas ọmọ Mālik - ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pe: Ojiṣẹ Ọlọhun - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - sọ pe: «Ẹ jẹ ki saafu yin o dọgba, nitori pe didọgba saafu ninu pipe irun lo wa»»

Meaning translation ·

Explanation

The meaning in a few plain lines

Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - n pa awọn olukirun láṣẹ lati maa to saafu wọn daadaa, ki apakan wọn si ma yọ siwaju ju apakeji lọ, ki wọn si ma sun sẹyin, ati pe didọgba saafu ninu pipe irun lo wa, ati pe wiwọ saafu si jẹ aayẹ ati adinku ninu rẹ.

Source
Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni
Download image

Saved at original quality