Hadith for the World
Tap the image to view it full size
Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ

Lati ọdọ Aishah iya awọn olugbagbọ ododo, ki Ọlọhun yọnu si i:

Available in 53 languages
«Lati ọdọ Aishah iya awọn olugbagbọ ododo, ki Ọlọhun yọnu si i: Òjíṣẹ Ọlọhun (kí ikẹ ati ọla Ọlọhun máa ba) aa maa se igbiyanju ni mẹwa igbẹyin iru igbiyanju ti kii se ninu awọn ọjọ miran.»

Meaning translation ·

Explanation

The meaning in a few plain lines

Ti mẹwa igbẹyin ninu osu Ramadan ba tide Anọbi (Ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba) aa maa gbiyanju ninu rẹ pẹlu ìjọsìn ati itẹle aṣẹ Ọlọhun, aa si maa se ọpọlọpọ awọn oriṣirisi iṣẹ o loore ati awọn oníranran iṣẹ daada ati ìjọsìn fún Ọlọhun eyi ti o pọ ju bi se ma ngbiyanju ni awọn ọjọ míràn lọ, ori bẹẹ nitori titobi ati ọlá ti nbẹ fún awọn òru náà ati nítorí wiwa òru abiyi.

Source
Muslim gba a wa
Download image

Saved at original quality