Hadith for the World
Tap the image to view it full size
Àwọn ìwà dáadáa ati awọn ẹkọ

Láti ọ̀dọ̀ Jubair ọmọ Mut'him- ki Ọlọhun yọnu si i- o sọ pe oun gbọ ti Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n sọ pe:

Available in 69 languages
«Láti ọ̀dọ̀ Jubair ọmọ Mut'him- ki Ọlọhun yọnu si i- o sọ pe oun gbọ ti Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n sọ pe: “Ẹni tí ba n ja okùn ẹbí ko nii wọ alujanna”.»

Meaning translation ·

Explanation

The meaning in a few plain lines

Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n sọ pe ẹni ti o ba gé ẹ̀tọ́ ti o jẹ dandan fun awọn ẹbí rẹ ti ko ṣe e fun wọn, tabi ti o fi suta kan wọn, tabi ti o ṣe aburu si wọn, o ni ẹtọ si ki o ma wọ alujanna.

Source
Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni
Download image

Saved at original quality