Hadith for the World
Tap the image to view it full size
Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ

Lati ọdọ Abu Huraira- ki Ọlọhun yọnu si i- pe ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- o sọ pé:

Available in 66 languages
«Lati ọdọ Abu Huraira- ki Ọlọhun yọnu si i- pe ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- o sọ pé: “Ọlọhun sọ pe: Maa na owó irẹ ọmọ Anọbi Adam, Ọlọhun maa fi òmíràn rọ́pò”.»

Meaning translation ·

Explanation

The meaning in a few plain lines

Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n sọ pe Ọlọhun sọ pe: Irẹ ọmọ Adam, maa ná owó- ninu awọn ìnáwó ti o jẹ dandan ati eyi ti a fẹ́- maa gbòòrò arisiki rẹ, maa si fi òmíràn rọ́pò, maa si ba ọ fi alubarika si i.

Source
Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni
Download image

Saved at original quality