Àwọn ìwà dáadáa ati awọn ẹkọ
Láti ọ̀dọ̀ Usaamah ọmọ Zayd- ki Ọlọhun yọnu si àwọn mejeeji- lati ọdọ Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- o sọ pe:
Available in 66 languages
«Láti ọ̀dọ̀ Usaamah ọmọ Zayd- ki Ọlọhun yọnu si àwọn mejeeji- lati ọdọ Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- o sọ pe: “Mi o fi fitina kan kan sílẹ̀ lẹyin mi ti o ni àwọn ọkùnrin lara ju àwọn obìnrin lọ”.»Meaning translation ·
Saved at original quality








