Hadith for the World
Tap the image to view it full size
Itan ìgbésí ayé

Lati ọdọ Anas ọmọ Mālik – ki Allāh yọnu si i – o sọ pe:

Available in 66 languages
«Lati ọdọ Anas ọmọ Mālik – ki Allāh yọnu si i – o sọ pe: Ojiṣẹ Ọlọhun – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – jẹ ẹniti o dara julọ ni iwa.»

Meaning translation ·

Explanation

The meaning in a few plain lines

Anabi – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – jẹ ẹniti o pe julọ ni iwa, o si tun gba iwájú nibi gbogbo iwa ati nkan daadaa, nibi ọrọ to daa, ati ṣiṣe daadaa, ati titu oju ka, ati mimu suta kuro ati nini atemọra rẹ lati ọdọ ẹlòmíràn.

Source
Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni
Download image

Saved at original quality