Hadith for the World
Tap the image to view it full size
Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ

Lati ọdọ ọmọ Umar ki Ọlọhun yọnu si awọn mejeeji:

Available in 58 languages
«Lati ọdọ ọmọ Umar ki Ọlọhun yọnu si awọn mejeeji: Lati ọdọ Anabi- ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a- dajudaju o kọ kuro nibi ẹjẹ jijẹ, o wa sọ pe: “Dajudaju ẹjẹ jijẹ o ki n mu oore wa, bi ko ṣe pe wọn maa n fi gba nnkan jade lati ọwọ ahun ni”.»

Meaning translation ·

Explanation

The meaning in a few plain lines

Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- kọ kuro nibi ileri, oun ni ki eniyan ṣe nnkan kan ni dandan fun ara rẹ ti Ọba aṣofin ko ṣe ni dandan fun un, o sọ pe: Nitori pe ileri ko ti nnkan ṣíwájú ko si lọ ọ lara, bi ko ṣe pe wọn maa n mu u jade lati ọdọ ahun ti ko ki n ṣe nnkan kan afi nnkan ti o jẹ dandan le e lori, ati pe dajudaju ileri ko ki n mu nnkan kan wa ti wọn ko tii kadara rẹ fun un.

Source
Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni
Download image

Saved at original quality