Hadith for the World
Tap the image to view it full size
Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ

Lati ọdọ Abu Hurayra - ki Ọlọhun yọnu si i - lati ọdọ Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - o sọ pe:

Available in 62 languages
«Lati ọdọ Abu Hurayra - ki Ọlọhun yọnu si i - lati ọdọ Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - o sọ pe: «Ọlọhun o nii gba irun ẹnikẹni ninu yin ti o ba ti ni ẹgbin lara titi ti yio fi ṣe aluwala».»

Meaning translation ·

Explanation

The meaning in a few plain lines

Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - ṣe alaye pe dajudaju ninu awọn majẹmu nini alafia irun ni: Imọra, nitori naa o jẹ dandan fun ẹni ti o ba fẹ ki irun ki o ṣe aluwala ti o ba ṣe pe ọkan ninu awọn nkan ti o maa n ba aluwala jẹ ba ṣẹlẹ si i; gẹgẹ bii igbẹ tabi itọ tabi oorun tabi nkan ti o yatọ si i.

Source
Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni
Download image

Saved at original quality