Hadith for the World
Tap the image to view it full size
Àwọn ìwà dáadáa ati awọn ẹkọ

Lati ọdọ Abu Hurairah, ki Ọlọhun yọnu si i, o gba a wa lati ọdọ Anabi, ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a, o sọ pe:

Available in 70 languages
«Lati ọdọ Abu Hurairah, ki Ọlọhun yọnu si i, o gba a wa lati ọdọ Anabi, ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a, o sọ pe: “Ko si nǹkan kan ti o ni apọnle ni ọdọ Ọlọhun - ti ọla Rẹ ga - ju adua lọ”»

Meaning translation ·

Explanation

The meaning in a few plain lines

Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ṣàlàyé pe ko si nnkan kan ninu awọn ijọsin ti o ni ọlá ni ọdọ Ọlọhun ju adua lọ; torí pé ó n bẹ ninu ẹ jijẹwọ ọ̀rọ̀ Ọlọhun ti ọla Rẹ ga, ati jijẹwọ ikagara ẹrú ati ìní bukaata rẹ si I.

Source
Tirmiziy ati Ibnu Maajah ati Ahmad ni wọ́n gba a wa
Download image

Saved at original quality