Hadith for the World
Tap the image to view it full size
Àwọn ìwà dáadáa ati awọn ẹkọ

Lati ọdọ Abdullahi ọmọ Amr- ki Ọlọhun yọnu si àwọn mejeeji- o sọ pe:

Available in 66 languages
«Lati ọdọ Abdullahi ọmọ Amr- ki Ọlọhun yọnu si àwọn mejeeji- o sọ pe: Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- kii se ọlọ́rọ̀ burúkú, kii sii mọ̀ọ́mọ̀ sọ ọrọ burúkú, o maa n sọ pe: “Dájúdájú ninu awọn ti wọn loore ju ninu yin ni àwọn tí ìwà wọn dára julọ”.»

Meaning translation ·

Explanation

The meaning in a few plain lines

Ko si ninu ìwà Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ki o maa sọ̀rọ̀ buruku, tabi wu iwa burúkú, kii sii mọ̀ọ́mọ̀ ṣe e, o si jẹ oníwà ńlá. Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- maa n sọ pe: Dajudaju ẹni tí ó ni ọlá jù ninu yin ni ọdọ Ọlọhun ni ẹni tí ìwà rẹ dara ju, pẹlu ṣíṣe dáadáa, ati ìtújúká, ati ki èèyàn ma fi suta kan ẹlòmíràn, ati fifi ara da suta lati ọdọ ẹlòmíràn, ati rírò pẹ̀lú àwọn èèyàn pẹ̀lú dáadáa.

Source
Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni
Download image

Saved at original quality