Hadith for the World
Tap the image to view it full size
Kuraani Alapọn-ọnle ati àwọn imọ rẹ

Lati ọdọ ‘Āisha – ki Ọlọhun yọnu si i– o sọ pe:

Available in 65 languages
«Lati ọdọ ‘Āisha – ki Ọlọhun yọnu si i– o sọ pe: Anabi – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – jẹ ẹni ti maa n ranti Ọlọhun ti ọla Rẹ ga ni gbogbo igba.»

Meaning translation ·

Explanation

The meaning in a few plain lines

‘Āisha iya gbogbo mu’mini – ki Ọlọhun yọnu si i – n sọ pe dajudaju Anabi – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – jẹ ẹni ti ojukokoro rẹ pọ gidi gan lori riranti Ọlọhun ti ọla Rẹ ga, ati pe dajudaju o jẹ ẹni ti maa n ranti Ọlọhun ti ọla Rẹ ga ni gbogbo igba ati aaye ati ìṣesí.

Source
Muslim gba a wa
Download image

Saved at original quality