YO
Awọn ẹkọ ofin sharia
Awọn ẹkọ ala
2 hadiths
Awọn ẹkọ olumọ ati akẹkọ
6
Awọn ẹkọ kika al-Quraani alapọnle
1
Awọn ẹkọ salamọ ati gbigba iyọnda
9
Awọn ẹkọ ọrọ sísọ ati didakẹ
12
Awọn ẹkọ jijẹ ati mimu
11
Awọn ẹkọ ati awọn idajọ irin ajo
4
Awọn ẹkọ orun sisun ati jiji
3
Awọn ẹkọ ala
2
Awọn ẹkọ abẹwo ati igba iyonda
3
Awọn ẹkọ sinsin ati yiyan
3
Awọn ẹkọ bibẹ alaarẹ wo
5
Awọn ẹkọ aṣọ wiwọ
8
2 hadiths
Lati ọdọ Abu Qatada - ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pé: Anọbi - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a - sọ pé: Lati ọdọ Ọlọhun ni ala daada ti nwa, bẹẹ ni láti ọdọ èṣù (Satani) ni ala burúkú ti nwa, ti ẹnikan nínú yín bá lá ala tí o se idẹruba fun un, ki o yáa fẹ atẹgun itọ ẹnu rẹ sí apá òsì, ki o si wa isọra pẹlu Ọlọhun nibi aburú ala náà, ti o ba se bẹẹ dájúdájú ala náà kòní kó ìnira ba a".
Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni
عن أبي هريرة رضي الله عنه قال: قال رسول الله صلى الله عليه وسلم : «من رآني في المنام فَسَيَرَانِي في اليَقظة -أو كأنما رآني في الْيَقَظَةِ- لا يَتَمَثَّلُ الشيطان بي».
متفق عليه. مسلم