YO
Imọra
Nnkan oṣu ati nifas ati ẹjẹ awaada
1 hadiths
Awọn ẹkọ bibiya bukaata
1
Awọn sunnah adamọ
3
Aluwala
8
Iwẹ
2
Aluwala elérùpẹ̀
1
Nnkan oṣu ati nifas ati ẹjẹ awaada
1
Pipa ibọsẹ-alawọ mejeeji ati nnkan ti o jọ wọn
2
1 hadiths
Lati ọdọ Umu ‘Atiyyah - ki Ọlọhun yọnu si i - o jẹ ẹni ti o gbe adehun (ibura) fun Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a -, o sọ pe: A jẹ ẹni ti kii ka omi ti awọ rẹ f'ara pẹ dúdú, ati omi alawọ iyeye lẹ́yìn imọra si nǹkan kan.
رواه أبو داود بهذا اللفظ ورواه البخاري بدون زيادة (بعد الطهر)