Hadith for the World
Tap the image to view it full size
Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ

Lati ọdọ Abdullahi ọmọ Umar- ki Ọlọhun yọnu si awọn mejeeji-:

Available in 58 languages
«Lati ọdọ Abdullahi ọmọ Umar- ki Ọlọhun yọnu si awọn mejeeji-: Dajudaju wọn ri arabinrin kan ti wọn ti pa ninu ọkan ninu awọn ogun ti Anabi- ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a- ja, nitori naa, ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a- kọ pipa awọn obinrin ati awọn ọmọde.»

Meaning translation ·

Explanation

The meaning in a few plain lines

Anabi- ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a- ri arabinrin kan ti wọn ti pa ni ọkan ninu awọn ogun ti o ja, nitori naa o kọ pipa awọn obinrin ati awọn ọmọde ti wọn o tii balaga.

Source
Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni
Download image

Saved at original quality