Hadith for the World
Tap the image to view it full size
Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ

Lati ọdọ shureih ọmọ Haani'i o sọ pé:

Available in 53 languages
«Lati ọdọ shureih ọmọ Haani'i o sọ pé: Mo bi Aishah leere, mo sọ pé: kini nkan akọkọ ti Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba) ma nṣe ti o ba wọlé rẹ? Aishah daun pe: yoo kọkọ rin pako.»

Meaning translation ·

Explanation

The meaning in a few plain lines

O tiwa ninu imọna Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati Ọla Rẹ máa ba a) pé kí o kọkọ rin pako ti o ba wọlé rẹ ni eyi keyi asiko ni oru tabi ọsan.

Source
Muslim gba a wa
Download image

Saved at original quality